''Iṣẹ mi ni lati gbe oku eeyan sori aga ki n si jẹ ki o dun un wo lati ya fọto,'' Ravindran lo sọ bẹẹ nipa ọjọ kinni to bẹrẹ iṣẹ. Ọmọ ọdun mẹrinla pere nii ṣe lọdun 1972 nigba ti baba rẹ Srinivasan to ...